Yoruba

Awon Onisowo Ke Gbajare Lori Aita Oja Bi Odun Ileya Se Ku Die

Pelu bi ose ku ojo mesan si Odun Ileya, awon ountaja l’oja Ogunpa, Mokola, Bodija, Aleshinloye tofimo Oja Sasa n’ilu ‘badan ni won ti so pe oja ko ta rara.

Okan l’ara ountaja aso, Arabirin Asisat Bashir, l’asiko ton ba akoroyin Oodua tiletoko s’oro, salaye pea won ero kan nkoja lati mo on ti won nta ni, won ni awon nduro de owo osu, ki won to le l’agbara lati ra nkankan fun Odun Ileya.

Ontaja miran, Arabirin Abiola Ogunniyi salaye pe itankale arun Covid-19 lo fa ipenija t’opo nkoju, owa ro ijoba ni gbogbo eka lati gbe eto kale ti yo mu awon eyan kuro ninu ise on osii.

Babatunde Salaudeen/Taiwo Akinola

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *