Igbeyawo je isopo okunrin ati obinrin ninu eyi ti ireti wa wipe lọkọ laya yoo maa se ọpọlọpọ nkan pọ.
Iku ojo kan naa tọkọtaya odun mejile laadorin nilu Abeokuta laipe yi lomu akoroyin wa Wale Oluokun bo sigboro se wadi lowo awon molebi ati ọjọgbọn awon nka to ro mo oru iku bee.
Abo re ree
pub-5160901092443552