Ileese Aare ti se koriya fawon Ijoba Ipinle, lati koju ija si gbogbo iwa odaran, a mo ki won ma te oju eto eni eyi ti awon daran-daran ni mole n’ipinle won.

Oludamoran pataki si Aare Muhammadu Buhari lori iroyin atoro tokan aralu gbongbon, Mallam Garba Sheu lo soro yi ninu atejade kan, to fisita lori igbese eyi ti Gomina Ipinle Ondo, Ogbeni Oluwarotimi Akeredolu gbe nipa fifun awon darandaran ni gbedeke lati ko aasa won kuro ninu igbo to je t’ipinle ohun.

Atejade naa so siwaju pe, yio nira fun Ogbeni Akeredolu lati tikara re le, ogunlogo awon darandaran ti won tii gbe gbogbo ojo aye won n’ipinle na, nitoripe awon odaran kan n sa pamo sinu igbo ohun lati fi huwa ibaje.

Ileese Aare ko sai fikun pe, eto abo to mehe ki se ti igun tabi egbe kankan.

Net/Ololade Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *