News Yoruba

Ajoyo Ojo Radio: Awon Ipenija to N Koju Awon Ileese ati Osise Agbohunsafefe

Ojo ketala ninu osu keji lodoodun ni gbogbo agbaye ma n se ayajo ojo Radio.

Ajo UNESCO lo kede ojo na,lati le tubo ma seto itaniji fun awon araalu ati awon ileese iroyin lori pataki radio lawujo.

Ninu akanse iroyin yi, Afolasade Osigwe, to pin pin awon ipenija to n koju ileese radio ati awon osise agbohunsafefe, lasiko yi.

Afolasade Osigwe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *