Ni bayi naa, awon alagbata epo nile Naijiria IPMAN, ni won ti gba awon  eeyan nile yi niyanju, lati yago fun rira epo pentrol pamo.

Agbenuso egbe IPMAN, Alhaji Suleiman Yakubu, lo soro amoran yi ninu iforowanilenuwo pelu akoroyin nilu Abuja.

Alhaji Yakubu bu enu ate lu bi awon eeyan se n sale lo ra epo pentrol nitoria ifoya, to sin mu ki awon ile epo kun fofo ju botiye lo.

O fowo idaniloju soya pe, gbogbo nkan ko nip e pada bo sipo, nitoripe won ti bere si nig be epo jade lawon ibuso ti won ti n gbe epo pentrol jade.

Akintunde/Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *