Yoruba

Ileise To n Pin Ina Oba, Yoo Mu Pipese Ero To n Ka Ina Oba Fonibara Lokunkundun

Ileese to n mojuto pinpin ina Oba nile Najiria NERC, ti so pe ko si onibara Kankan ti won yo ma mafun ni owo ti yo ma san, nitoripe ileese to n pin ina kuna lati fun won ni ero ti yo maa ka iye ina oba ti won ba ti lo.

Ninu atejade kan ti ilese NERC, fisita nilu Abuja ni oro yi ti jeyo, pelu atokasi pe oniruru aroye ni awon ti ri gba ni o ku bi osun merin ti odun 2020 yo kogba wole, lori aiteteri ero to n ka iye ina oba teeyan lo rigba.

Lati wa wojutu soro ipenija yi ileese ohun wa so pea won yo mu gbigbe ero yi lo kunkundun fawon onibara, labe eto ti ijoba apapo gbe kale lati pin ero yi lopo yannturu.

Ibrahim/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *