Yoruba

Ilese Olopa Safihan Awon Metadinlogoji Tiwon Furasi Gege Bi Odaran ni Ibadan

Oga agba nilese olopa ipinle Oyo, Arabinrin Ngozi Onadeko tikesi awon araalu lati mafi irin kooto tiwon ba fefin layika too ajo eleto abo leti.

 Arabinrin Onadepo so eyi lasiko to nfi awon ti won furasi gegebi odaran , metadinlogoji otooto han foniruru esun bi ijinigbe idgunjale biba omode si ise koto, jibiti ori ero ayelujara, atawon iwa odaran min.

O salaye pe, awon osise na se aseyori nidi fifowo ofin mu awon eeyan wonyi, nipase sise ise won bise ati iroyin tawon araalu fi to won leti.

Arabinrin Onadeko salaye pe niwon igba ti ilese naa tikede wipe koni fayegba iwa odaran bo ti wu o mo, yoo ridajupe awon olugbe ipinle Oyo nsun harun pelu eto abo to gunmo.

 Alakoso Olopa nipinle Oyo wa salaye pe pelu oniruru ona tajo naa ti gbekale lati towo awon odaran boso nipinle Oyo, o se pataki kawon araaalu maa se kare nidi fifun ilese olopa lawon iroyin to yoo mu ise won kasejari.

O wa seleri lati fawon tiwon furasi ohun sowo si ile ejo leyin iwadi togumo.

Pupo ninu awon tiwon furasi ohun lawon jebi esun tiwon fi kan won, amo ti bebe wipe ka se won jeje.

Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *