News Yoruba

Ẹgbẹ́ Àwọn Dókítà Onímọ̀ Ìsègùn Òyìnbó Loodi Ikú Aláboyún Mọ Bí Àwọn Èyàn Sen Pọ̀si Lórílẹ̀ Èdè

Àwọn onímọ̀ nípa ètò ìlera ti sọ pé bí ikú aláboyún seń pọ̀si nílẹ̀yí, lanise pẹ̀lú isẹ́ on òsì tófimọ́ bí èyàn se pọ̀ lápọ̀jù.

Ìgbìmọ̀ tón rísí ìkànìyàn, ẹgbẹ́ àwọn dókítà nílẹ̀yí, sọ pé àwọn on àmúsẹrọ̀ tó wà nílẹ̀ yí, ni kò tó láti sètójú àwọn èyàn tó lé ní milliọnu makànlá niye, ìdínìyí tó fi yẹ kámojútó débá bí àwọn èyàn sén pọ̀ láti yàgò fún míma fi gbogbo gbà yá owó.

Alága ìgbìmọ̀ ọ̀hún, dókítà Ejiro Iwoha se lálàyé pé, àpọ̀jù àwọn èyàn tí kò si si ìrónilágbára ètò ọrọ ajé, ló ń mú kí ìwà ọ̀daràn ma peléke si, àiní isẹ́lọ́wọ́ tífimọ́ ikú ìyálọ́mọ.

Dókìtà Iwoha wá ńfẹ́ kí àwọn ọkùnrin náà ma mójútó kí wọn si kópa nínú ètò ìfètòsọ́mọbíbí, kí wọ́n sì dábòbò ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin papa lórí ìlera àsìkò ìbímọ.

Ó wá tẹnumọ pé yio dára káwọn ọkùnrin náà ma lọ fún ètò ìfètòsọ́mọbíbí káwọn obìnrin si yan èyí tó wù wọ́n.

Alamu/Afọnja  

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *