Yoruba

Gomina Seyi Makinde Bawon Musulumi Yo Fun Biwon Se Foju Ganni On Ka Osu Tuntun Hijrah 1443

Gomina Ipinle Oyo, Onimoero Seyi Makinde ti bawon Musulum to nbe yika Ipinle yi ati jakejado Agbaye yo, lori biwon tunse foju ganni ojo akoko tinu osun Muharram ti Hijrah 1443.

Gomina Makinde wa ro awon Musulumi lati maa samulo iwa irele, ati suuru to fimo nini ifarada eyi ti Anobi Mohammed kowon lakoko to kuro nilu Makkah losi Medina.

Ninu atejade takowe Agba feto iroyin fun Gomina, Ogbeniu Taiwo Adisa fisita, sope Gomina fe kawon Musulumi je ki Pataki osun onka Hijrah yii maa farahan ninu igbeaye won.

Ko sai tenumo pe isejoba oun ti setan lati mu ayipada rere bawon ohun amayederun ati ti igbayegbadun araalu eyi to n gunle lowolowo bayi nipinle Oyo.

Adebisi/Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *