Asaaju awon eeyan ile Biafra Nnamdi Kanu ti bebe pe oun ko jebi esun ti ijoba apapo fi kanan.

Loni ti won n tesiwaju ninu ipejo re, nile ejo giga nilu Abuja lori esun igbesunmomi ati idite mo ijoba eyi ti ijoba apapo se atunto le lo n lose to koja lati soo die sun ipele meje.

Kete leyin to bebe pe oun ko jebi ni Adajo pa lase pe to si wa lahamo iko otelemuye DSS.

Won si ti sun igbejo siwaju di ojo kewa osu kokanla odun 2021.

Ololade Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *