Alákoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ìgbanisísẹ́, Ọ̀mọ̀wé Chris Ngige ti sọpé gbogbo ìgbésẹ̀ lóyẹ ní gbígbé lójúnà àti fòpin sí ọ̀rọ̀ àinísẹ́se nílẹ̀ Nàijírìa.

Ọ̀mọwe Ngige sọ̀rọ̀ ọ̀hún lásìkò tó ń sí ibùdó ori ẹ̀rọ ayélujára lórí ọ̀rọ̀ ìpèsè isẹ́ tàtúnse ti débá, eléyi tí wọ́n pe ní National Electronic Labour Exchange Centre, fún díkẹ́kun ìpèníjà tón kojú àwọn tón wásẹ́.

Alákoso ọ̀hún wá pé fún lilo ọgbọ́n àtinúdá ọ̀hún ẹnawo kopinle dé bá isẹ́ òhun òsi, àirísẹ́se àti láti fòpin sí báwọn èyàn ilẹ̀yí sen rọna àti kúrò nílẹ̀ baba wọn.

Blessing Ọkareh/Ayodele Ọlaọpa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *