News Yoruba

Awon To Ku Die Kaato Fun Janfani Kaadi Ajo Adojutofo Ilera Nipinle Osun

Gomina ipinle osun, Ogbeni Adegboyega Oyetola ti bere pinpin lopoyanturu, kaadi ajo adojutofo ilera fawon bi olugbe bi egberun mokandinladorin ati orinle rugba odin meje.


Atejade latowo akowe eto iroyin fun gomina , Ogbeni Ismail Omipidan, salaye pe ajo adoju to fo ipinle osun to saseyori ori fiforuko egberun mokandinladorin ati orinlerugba odin meje awon to ku die kato fun sile ti won si tin janfani eto ilera lati bi odun meji labe ajo ton risi eto inawo eto ilera to muna doko.


Ogbeni isamil sope ijoba to san owo iranwo to wa fun ppipese eto ilera ati itoju fawon to ku die kato fun nipinle naa lofe lofe to si lo so ipinle naa di ipinle keji nile Nigeria lati se bee.

Ajadosu/ Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published.