Aare ile yi nigba kan ri, oloye Olusegun Obasanjo ati Sultan tilu Sokoto, Alhaji Sa’ad Abubakar pelu awon eekan nile  yi ti sekilo lori tito wo oselu bo eto  aabo emi ati dukia awon omo ile yi.

Won sekilo yi nibi eto ijiroro olojo kan to da lori eto aabo, eyi ti ajo kan lagbaye to wa fun ifesemule eto alaafia se agbekale re pelu ifowosowopo ajo kan ton n je vision africa, eyi to waye nilu abuja.

Oloye Obasanjo salaye wipe igbiyanju ileese oloogun  nikan ko to lati fopin si eto aabo to mehe, o se afikun e ni pe ijoba gbodo tele ilana to ye lati wagbo dekun fun isoro naa.

Suitan naa komimu lori bi eto aabo se n mehe kaakiri ile yi, o salaye wipe aabo emi ati dukia araalu pon dandan.

 Ninu oro tie, aare egbe  awon omoleyin christy nile yi, eniowo samson ayokunle mo awon asiwaju pe ki won fese aseyori nidi eto aabo mule.

Net / Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *