Bi odun ileya ti se wole de, abewo sawon ibudoko fihan wipe awon ero iwoko o fi gbogbo ara rin irin ajo nitori wipe eta horo lawon ti won fe rin irin ajo kuro nilu Ibadan lo sawon apa ibomiran nile yi.
Abo iroyin Dayo Adu to sabewo sawon ibudoko naa ree lati enu Oluwayemisi Owonikoko.
pub-5160901092443552