Home Posts tagged Alade Lawal
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ àti ẹgbẹ́ òsìsẹ́ ńfikùnlukùn lórí owó òsìsẹ́ tuntun

Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ yíì àti ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ ńfikùnlukùn láti fọ̀rọ̀jomito ọ̀rọ̀, lórí àlékún owó osù òsìsẹ́ tówà lákàsọ̀ tókéréjù ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n náirà. Ìpàdé yíì ló ń wáyé lẹ́yìn ìpàdé èyí tíwọ́n se lána òdeyi níbi tẹ́gbẹ́ àwọn òsìsẹ́ ti fi ìpinu wọn lórí àlékún náà hàn, tí ìpàdé òní sì Continue Reading