Home Posts tagged àwọn ẹ̀rọ arabiasa
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ra àwọn ẹ̀rọ arabiasa láti mú kámugbòrò débá ìsèjọba

Gómìonà Seyi Makinde tìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, ti se ìfilọ́lẹ̀ ìsí àkọ̀kọ̀, sísètò ìjọba lórí òpó ẹ̀rọ ayélujára pẹ̀lú ẹ̀rọ ayábiasa tó lé ní ẹgbẹ̀rún kan níye, tí àwọn ilésẹ́ ìjọba àti ẹ̀ka yo ma lo nípinlẹ̀ yí. Ètò ọ̀hún lówáyé níbùdó ìmọ̀ ẹ̀rọ ayélujára tó wà ní secretariat Agodi ìbàdàn. Gómìnà Continue Reading