Home Posts tagged bíba dúkia ìjọba jẹ́
Yoruba

Alákoso ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ sèkìlọ̀ fáràlú láti yàgò nídi bíba dúkia ìjọba jẹ́

Alákoso ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Nwachukwu Enwonwu ti sèkìlọ̀ fáwọn ọlọ́kadà, àwọn òntàjà àtàwọn onísẹ́ọwọ́ lọ́jà Agodi Gate láti dẹ̀hìn nídi bába àwọn ǹkan ìníì ìjọba jẹ́ àtàwọn ilésẹ́ ọlọ́pa. Nínú àtẹ̀jáde tálukoro ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Gbenga Fadeyi fisíta Continue Reading