Home Posts tagged Delta Variant
Yoruba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn Gùnlé Ìlanilọ́yẹ̀ Lórí Ẹ̀yà Àrùn Covid-19 Min

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti gùnlé ìlanilọ́yẹ̀ lórí àyẹ̀wò láwọn ìjọba ìbílẹ̀ márun tí àrùn covid-19 ti nwopo pẹ̀lú àmọ̀nràn fáwọn olùgbé ibẹ̀ láti ríì dájú wípé wọn tẹ̀lé ìlànà ìlera lọ́nà àti dáàbòbò ara wọn lórí ẹ̀yà TUNTUN ÀRÙN COVID-19 tí a mọ̀ si Delta. Alákoso fọ́rọ̀ ìlera nípinlẹ̀ Ògùn, Dókítà Tomi Coker ló sọ̀rọ̀ […]Continue Reading