Ibẹ̀rù bojo ìkọlù látọ̀dọ̀ àwọn molọ kólóun kígbe tón sàkóbá fún kárà kátà nílu ọ̀yọ́ láti àná, ló sin tẹ̀síwájú lóòrọ òní. Akọ̀ròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria tón tópinpin ìsẹ̀lẹ̀ yi jábọ̀ pé, àwọn ilé ìfowópamọ́ lágbègbè náà ní àwọn kò ti sí ilẹ̀kùn rẹ̀, láti má da àwọn oníbarà loun lẹ́yìn tí wọ́n Continue Reading
Gomina ipinle oyo, onimo ero seyi makinde ti so pe isejoba re, yo tesiwaju lati ma fi awon liana lele ti yo mu keto oro aje gboro si nipinle yi. O soro yi lasiko, ton forowero pelu awon asaju ninu oja ati pelu awon egbe onise owo yika ipinle oyo, eyito waye nilijoba to wa […]Continue Reading