Home Posts tagged Ijoba
Yoruba

Ijọba Ipínlẹ̀ Bayelsa Sèlérí Amúsẹ Abọ̀ Igbìmọ̀ Lórí Awọn Olọ́pa

Igbìmọ̀ atọpinpin elétò ìdájọ́ se se aráàlu  nisekuse àtàwọn ìsẹ̀lẹ̀ miin tó fara pẹ́ tí dába owó tó tó billiọnu mọ́kànlélógún naira fún sisan owó gbà mábinú fáwọn tí ọlọ́pa bá gbẹ̀mí wọn lọ́nà àitọ́ pẹ̀lú àwọn ikọ̀ agbófinró mii. Alága ìgbìmọ̀ náà, adájọ́ fẹ̀yìntì Young Ogola ló fojú ọ̀rọ̀ yí Continue Reading