Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sáwọn olùgbé láwọn agbègbè tí ẹ̀kún omin ti ńsọsẹ́, láti kúrò níbẹ̀ náà láti dènà lílúgbàdì ẹ̀kún omi, bí ìjọba se ńgbé ìgbésẹ̀ láti pinwọ́ ẹ̀kún omi láwọn agbègbè náà. Alákoso fọ́rọ̀ àyíká àtàwọn ohun àlùmọ́nì, ọ̀gbẹ́ni Kẹhinde Ayọọla, sọ èyí lásìkò tó sàbẹ̀wò Continue Reading