News

Ọba alayé fọnrere ìdàgbàsókè nípasẹ̀ ìsọ̀kan

Aláafin tìlú Ọyọ, Ọba Lamidi Adeyẹmi ti bèèrè fún ìfẹsẹ̀múlẹ̀ àláfìa àti ìsọ̀kan láarin àwọn olósèlú tófinàwọn Ọba alayé kérongbà ìdàgbàsókè tónítumọ̀ lè ba wà sí ìmúsẹ nílẹ̀ Nàijírìa.

Níbi ìfilọ́lẹ̀ àwọn asojú àtàwọn ọmọ ẹgbẹ́ tuntun tófimọ́ ìfilọ́lẹ̀ àwọn isẹ́ àkànse tuntun tẹ́gbẹ́ ọmọbíbí ìlú ìbàdàn CCII, tówáyé nílẹ̀ ìbàdàn ládugbò Òkè-Arẹmọ.

Nígbà tó ń sèfilọ́lẹ̀ kíkọ́ ilé-isẹ́ ọlọ́pa tuntun, èyí tẹ́gbẹ́ àwọn ọmọbíbí sagbátẹrù ẹ̀, Ọba Adeyẹmi sàlàyé pé, àláfìa àti ìsọ̀kan sepàtàkì, láti mú kerongba ìdàgbàsókè èyíkèyi orílẹ̀dè wa sí ìmúsẹ.

Kẹmi Ogunkọla/Lillian Ibomor

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *