Yoruba

Onímọ̀ bèèrè fún ìkọ́sẹ́mọsẹ́ nídi ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́

Wọ́n ti gbàwọn tóngbóhùn sáfẹ́fẹ́ látorí ẹ̀rọ ayélujára àtàwọn olùdásílẹ̀ rẹ̀ níyànjú láti jẹ́ akọ́sẹ́mọsẹ́ nídi isẹ́ tíwọ́n yàn láayo.

Alájutó àgbà ilé-isẹ́ ẹlẹ́rọ amìnlújìnjìn Premier tó wà nílu ìbàdàn, Ẹniọ̀wọ̀ Niyi Dahunsi ló gbọ̀rọ̀ àmọ̀ràn yíì kalẹ̀, lákokò tó ń gbéwe àpilẹ̀kọ kan kalẹ̀ níbi ayẹyẹ àkọ́kọ́ ilé-isẹ́ Radio orí ẹ̀rọ ayélujára, Maranatha.

Ẹniọ̀wọ̀ Dahunsi tó sàlàyé lórí ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tílànà àtijọ́ àti tòde òní, sọ pé, ilé-isẹ́ Radio náà, gbọ́dọ̀ máà sàmúlò ìlànà ojúlówó ètò ìkọ́ni atojosepọ tó dánmọ́rán láarin rẹ̀ àtàwọn aráalu tóngbọ.

Kẹmi Ogunkọla/Modupe Tọba

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *