Yoruba

Ile Igbimo Asofin Ipinle Ogun da awon Alaga Ijoba Ibile pada s’ipo

 Ile Igbimo Asofin Ipinle Ogun ti gbese kuro lori ofin lo’rokunnle ti ijoba to kuro nipo fawon alaga ijoba ibile ogun ati ijoba ibile alabode metadinlogoji towa n’ipinle naa.

Igbese naa lo tle abo iwadi igbimo teekoto ile lori oro ase lorookun nile fawon todipo ase mu ohun.

Adari ile Ogbeni Kunle Oluomo ro awon alaga naa lati ridajuwipe won seto isuna won pelu akoyawo biwon se npada sipo.

Awon laga tiwon o we yan Kankan gbodo farahan niwaju igbimo oluwadi ijoba fun iwadi to kunna.

Kemi Ogunkola/Wale Oluokun

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *