Yoruba

Onimo nipa oro aabo se atotonu lori ifesemule aabo

Awon toro abo gberu ti pejo se idanileko lori igbese lati gbogunti iwa-ibaje, WAI Brigade, lori olopa agbegbe eyiti ajo olutaniji araalu sojuse won N.O.A. nipinle Oyo s’agbekale re.

Oludanileko nibi eto naa, oluranlowo pataki fun Ogagun agba fajo abo araeni l’aabo-ilu ekun kefa, ACG Shem Obafaye ro awon osise WAI Brigade yii lati maa sise won bi ise.

Ninu oro to firanse, Olubadamoran pataki fun Gomina ipinle Oyo onimo ero Seyi Makinde f’oro abo Alakoso nilese Olopa toti fehinti nilese Olopa, Ogbeni Fatai Owoseni ro awon osise WAI Brigade naa lati ma gbe iwa omoluabi woo nigbagbo.

Kemi Ogunkola/Rasheedah Makinde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *