Yoruba

Apero àwọn Gómìnà pè fún ilaniloye lórí ọ̀rọ̀ kobakungbe

Apero àwọn Gómìnà nílè yíì, NGF, tí gba ilé ìgbìmò asofin àgbà ilé yíì níyànjú láti gunle ìpàdé ìta gbangba lórí àbá òfin kan tonise pẹ̀lú sísọ ọ̀rọ̀ kobakungbe láti rí dájú pé, wón gbo èrò aráàlú lórí àbá òfin náà.

Alága Apero àwọn Gómìnà ohun, tí í ṣe Gómìnà ìpínlè Sokoto, Aminu Tambuwa ló gbòòrò ìyànjú náà kalẹ lákòókò tó dáhùn ọkàn ó jokan àwọn ìbéèrè latodo àwọn oniroyin, lópin Apero ohun tó wáyé nilu Abuja.

Gómìnà Tambuwa kò sai tún gbawon asofin apapo náà nimọ̀ràn láti bọ̀wọ̀ fero aráàlú lórí àbá òfin òhun, pẹ̀lú àlàyé pé, àwọn Gómìnà yóò ṣe atileyin lórí àwọn nkan tó lè mú agbega bá owó tí wọn ń pawolè labele ton tí ìjọba Àpapọ̀ àtàwọn ìjọba Ìpínlẹ̀

Kemi Ogunkola/Adebisi

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *