Yoruba

Ilese Radio Nigeria Seleri Ajosepo Pelu Ajo BAYI Lati Gbogunti Ise

Ajo kan ti kii se tijoba tamosi Bode Akindele Yield Initiative, BAYI, so pe bi aadota awon eniyan ni yoo janfaani idanileko nipa eto ogbin lodun 2020 tawa yii lati madinku ba airise se to gbogo nile yii.

Oludari agba ajo BAYI, Ojise Olorun Adetunji Agbgoola lo soro yii di mimo lakoko abewo awon alabojuto ajo naa silese Radio Nigeria, Ekun Ibadan.

Ojise Olorun Agboola to so pe awon odo nlowo ninu awon iwa kan lawujo nitori aimo iwulo ebun tolorun fi jinkin won, wa so dimimo pe afojusun ajo BAYI ni lati lowo sawon ojokan ise aje teyi sile se se nipase ifowosowopo pelu ile ise Radio Nigeria.

Nigba ton naa nsoro, Oludari ile ise Radio Nigeria Ibadan, Alhaji Mohammed Bello sope ile ise Radio Nigeria ti setan lati gunle ajosepo pelu ajo BAYI fanfaani awon odo ile Nigeria.

Ajo BAYI loje ajo tafoju sun re je kiko awon odo lawon ona tiwon yoo file da duro fun ara won leka idokowo.

Ogunkola/Famakin

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *