Yoruba

Awon Osise Ijoba Pada Senu Ise Nipinle Oyo Lehin Isinmi kannpa

Osise ijoba, nipele ese kejila si isale nipinle Oyo bere ise pada loni,  leyin ase ti ijoba ipinle pa saaju, to fi ti gbogbo awon ile ise pa nitori ajakale arun covid-19.

Akoroyin ile ise Radio Nigeria eniti o wo bi nkan ti se nlo si nileese ijoba to was ni Agodi nilu Ibadan jabo wipe awon osise eleto aabo ara eni laabo ilu ati awon osise OYRTMA ni won wa lawon enu iloro mejeeji to wo ibe.

Akoroyin wa tun jabo wipe, awon oun elo ifowo ni won gbe sawon enu ona ile ise kokan ti awon ti won ta ibonu naa nlo asiko ohun lati sare lenu ona ile ise ijoba naa.

Illekun enu iloro ti won ti gbe ti pa nigbati won ti ile ise ohun ni won ti si pada fun lilo bibo.

Die lara awon osise ti akoroyin ile ise R/N ba soro ni inu awon dun lati pada senu ise leyin isinmi fidimole olosu meta, ti won wa seleri ati tera more won.

Ijoba ipinle Oyo lo gbe ile ise ijoba re ti pa lojo ketadinlogbon osu keta ti won si si die fun and to wa ni ipele ketala soke lojo ketadinlogbon osu kerin eyi tii se ara igbese lati dena itankale arun covid-19.

Yemisi Dada

                                 

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *