Ijoba Apapo ti yi ipinu re pada lori sisi ilewe fun awon akeko kan.

O sope kosi ilewe Kankan ti yio se idanwo asekagba ti won ni yow aye larin ojo karun osu kejo ati ojo karun osu kesan odun yi.

Alakoso feto eko, Ogbeni Adamu Adamu nigba ton baa won akoroyin soro leyin ipade awon igbimo alase eyi ti Are Muhammadu Buhari lewaju re, sope ilewe Kankan nile naijiria koni si pada rara titi di igba ti abo yow a nitori arun Covid-19.

O ni awon akeko to wa ni ipele to gbeyin lati se idanwo asejade nile eko girama ni koni pada si ilewe, eyi to simu ayipadan ba ikede ti won setele.

Ogbeni Adamu fikun oro re pe ajo ton se idanwo asekagba, eyini WAEC, kooni yo so asiko ti ilewe Najiria yow ole pada.

Ewe, aralu kan ti gboriyin fun Ijoba Apapo lori ipinu re toyi pada lori iwole awon akeko lorile ede yii.

Nigba ton ba akoroyin ilese Radio Nigeria soro, Ogalewe Ijoba Apapo Lobinrin, Odogbolu Nipinle Ogun, to ti feyinti, Ogbeni Gbolahan Oladoyinbo, sope ipinu toyipada yi, loje eyi to dara.

Ogbeni Oladoyinbo tokasi pe yio soro fawon akekom lati tele awon ofin didena itankale arun Covid-19.

O fikun pe bi iye awon toni arun Covid-19 se nposi nile yi lawon ipinle tiwon ti si ilewe pada loye ki won tun ero won pa fun aabo to peye fawon eyan.  

Ololade Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *