Yoruba

Awon Olugbe Olorunda Abaa Kegbajare Sita Lori Ipo Ti Opopona Won Wa

Awon olugbe ati awako to nrin ona Olorunda Abaa ti won ti nfojuwina isoro lati de ibiti won nlo nitori ipo ti ko wu oju ri ti ona agbegbe naa wa.

Ipo ti ona yi wa ko seyin bi ijoba ipinle Oyo ti se gba ise agbase ona Basorun/Akobo lowo agbase se losu die seyin.

Nigbati won nba akoroyin ile ise R/N soro, meji lara awon olugbe agbegbe Ogbeni Adeyemi Oyerinde ati Remi Ahmed sapejuwe ohun ti oju won nri gegebi ohun ti o ko siso ti oko won is nfojoojumo baje

Awon olol weo bu enu ate lu bi nkan ti ri nitoripe o ti koba owo ti won npa nitori lilo bibo won loju ona naa ti dinku.

Akoroyin R/N to sabewo si agbegbe naa rii wipe awon oko nla-nla ri si awon ibikan lopopona naa leyi ti o mu ki lilo bibo pakaso loju ona naa to si ti fa sun kerefakere nibe.

Awon olugbe ibe wa kesi Gomina Seyi Makinde lati gbe ise opopona Basorun-Akobo fun agbasese ati ki won be atunse ona Barrack-Olorunda Abaa lati lee mu ki inira ti awon eniyan nkoju dinku.

Busari/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *