Yoruba

Egbe Osise Sekilo Fajo To N Pese Ina Oba Lori Ipese Ina Oba Toduro Re

Egbe awon osise leka to n pese ina oba lorile ede Nigeria NUEE, ti sekilo fun ile ise ton pin ina oba nile Nigeria, DISCOS, lori bibenu ate lu terutomo lorile ede Nigeira.

Akowe Apapo fegbe ohun Ogbeni Joe Ajero, sekilo be nilu Eko, pelu alaye pe awon omo ileyi ko lee maa sanwo ina oba tiko se deede.

Okoju oro si ile ise to n pinna oba lori aifikun aayan re, leyi ton fi gbogbo igba da ina oba tiwon takoto siwon pada latowo awon ile ise to n pese ina oba ohun nile Nigeria.

O fikun oro re pe aikoju osunwon won to, lon sokunfa eru tinbe lorun ero ton pinna eyi toto was Asorun, jakejado ileyi toti baje tiwon ko si paaro re. Aminat Ajibike/Elizabeth Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *