Yoruba

Igbakeji Aare Fokan Awon Eeyan Bale Lori Ireti Ojoola Rere Ile Nigeria

Igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo sope pelu ipenija to nkoju ile yii, lati ogota odun toti gba ominira re, o se Pataki lati fojusun ojo-iwaju pelu ireti.

Ojogbon Osinbajo so eyi nibi eto idanileko Egbe NASFAT, fawon odo, pelu akori “Isokan, Alafia Ati Aseyori Ile Nigeria”.

Igbakeji Aare sodi mimo pea won odo ni ojuse toopo lati se nidi sisa mulo ati apinkari ohun alumoni.

Gege bi Ojogbon Osinbajo se so pe pupo iberu-bojo tawon eeyan ile yii nkoju ni rogbodiyan, aile to si ohun amayederun botiye , amo oni awon eeyan ile yi kogbodo kaare nidi ifesemule isokan ati idagbasoke ile yii.

Aminat Ajibike/Elizabeth Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *