Yoruba

Ajo FRSC gba awon awako nimoran lori ona adinku ijamba oko

Won ti gba awon iko Special Marshal nimoran pe ki won o ma kaare ninu igbiyannju won nidi ati dena ijamba oko loju popo.

Oludari ajo eso oju popo nile yi, eka tipinle Oyo, Arabinrin Winifred Chukwurah lo soro iyanju yi nibi idanileko kan to way nilu Ibadan fun awon olori eka ajo naa.

Oludari ajo ohun eni ni Corps Marshal Olalekan Morakinyo soju fun fi emi imore han sawon Special Marchal fun bi won se n mu ki adinku ba ijamba oko loju popo lati osu kinni de osu kejila, o wa ro won pe ki won tun maa se amulo eko ti won tun ko nibi idanileko yi.

Alamojuto iko Special Marshal nipinle Oyo, omowe Ebenezer Okebukola tokasi ere asapajude lilo ero ibaraenisoro pelu wiwa oko atawon iwa ailakasi miin gege bi ohun to n se okunfa ijamba loju popo.

Omowe Okebukola wa ro awon iko Special Marshal pe ki won maa se ise won bi ise, o tun ro awon awako pe ki won maa feso se asiko osu ba ba ba taa wa yi.

Babatunde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *