Yoruba

Ipo ti awujo wa lo n je ki arun opolo peleke si nile yi – Awon onimo isegun

O se Pataki lati maa tete dide iranlowo si eni yoowu tawon eeyan ba sakiyesi pe iwa ati isesi re deede yipada lojiji.

Eyi lo je ohun ti awon olukopa lori eto Focal Point, nilleese Radio Nigeria soro le lori nipa idi to fi ye kawon eeyan dokowo seka eto iwa opolo.

Onimo isegun itoju arun opolo, Dokita Yinka Adefolarin salaye wipe isoro atije atimu ti wopo lawujo ati isoro ajakale arun Covid-19 to n ja ranin ranin lagbaye ti so opo eeyan di akurete.

Ninu oro ti e naa, onimo Isegun opolo Dokita Kola Okunade to awon arralu pe ki won yago fun egbogi to ba le tawo si opolo won.

Awon onimo isegun yi w ape fun titunbo dokowo si eka yi lati fi koju ipenija yi nipa bi akosile se fihan pea won alarun opolo po nile Nigeria ti a ba se igbilewon re pelu awon orileede miin nile Africa.

Babatunde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *