Àkànse ìpàdé kan láti fi bu ọlá fún ọ̀gá ilé-isẹ́ Radio Nigeria ẹkùn ìbàdàn, tó fẹ́ fẹ̀yìntì lẹ́nusẹ́, Àlhájì Muhammed Bello sì ń lọ lọ́wọ́ ní bgọ̀ngàn studio tó wà nílé sẹ́ náà l’ádugbò Dùgbẹ̀ nílu ìbàdàn.

Alákoso fétò ìròyìn nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, Àlhájì Wasiu Ọlatunbọsun, àtàwọn olórí ẹ̀ka ìròyìn nílé’sẹ́ náà tó ti fẹ̀yìntì niwọ́n péjú pésẹ̀ síbi àkàse ìpàdé ọ̀hún, èyí tẹ́ka ìròyìn níle’sẹ́ náà sagbátẹrù ẹ̀.

Àlhájì Mohammed Bello ni yóò fẹ̀yìntì lẹ́nu’sẹ́ ọba lósù tó ńbọ̀, lẹ́yìn tó ti pé ọgọ́ta ọdún.

Ọlaolu Fawọle/Fọlakẹmi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *