O se Pataki fun ijoba lati fowokun owo ori siga, lati le madinku baa awon arun to njeyo nidi siga mimu lorileede yi.

Awon oluwadi kan lo soro yii nibi eto idande kan lori okoowo siga lorileede yi, eyi to waaye ni gbongan apero nile eko giga vasity Ibadan.

Ogbeni adedeji adenitan, onimo nipa ise iwadi nibudo ti won ti n ko nipa eto oro aje nile African CSEA, kesi ijoba lati satungbeyawo owo-ori siga atawon ilana amujo sii, lati madinku ba awon ipenija ti ma tarare suyo.

O salaye pe orileede yi naa owo lopo sawon arun to ntara siga suyo ju owo to n tara re rii loo.

Ninu oro onimo ise iwadi mu, lati CSEA ogbeni IRAOYA Augustine tokasi pe ona abayo kan soso lati wojutu si ipenija siga mimu nile yi ni fifowo le owo ori re.

O salaye pe ti alekun ida marundinlogbon bale ba owo ori siga yoo madinku ba, iku, jejere, ati ona tawon eeyan ngba lugbadi arun.

Awon olukopa war o ijoba atawon torokan ati gbe igbese tooye nidi mimu adinku ba siga.

Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *