Yoruba

Igbimo Amuseya Ijoba Apapo Farun Covid-19 ni Kosi Isede Kankan Lode

Igbimo amuseya ijoba apapo farun covid-19, PTF, ti ro eeyan ile yii, lati koti ikun si iroyin ofege to wa lori ero ayelujara pe igbese konilegbe mi yoo tun waye.

Oludari ajo PTF Dokita Sani Aliyu so eyi nilu Abuja.

Omowe aliyu sope Ijoba ni imoo si ipaa ti monilegbe titun lenu ori eto oro aje, eyi to ni omu sepataki fawon eeyan ile yii lati maa paa ofin abo moo.

O wa ro awon eeyan awujo lati koti kun si iroyin ofege naa kiwon si maa ba kara-kata won lo.

Ikominu ti wa n waye lori booya isede min yoo tun wa, bi owoja arun covid-19 se ntan fun igbakeji

 Net/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *