News Yoruba

Gomina Makinde Sepade Po Pelu Awon Toro Aabo Kan Lagbe-Gbe Ibarapa

Gomina Seyi Makinde tipinle Oyo ti sepade po pely awon torokan lagbegbe ibarapa ni ipinle yi lori bi oro aabo se mehe lagbegbe ibe.

Gomina Makinde nigbati o nsoro nilu Igbo Ora pelu awon eniyan so wipe oun ni imolara irora ti won nkoju, o wa ni abewo naa yio jeki oun wa ojutu si isoro oro aabo toti ndi gbonmo-gbonmo lagbegbe naa.

O salaye wipe ijoba ti fowosi ifilole igbimo ti yio risi oro alaafia ati aabo nijoba ibile naa to wa tenumo pe ijoba ipinle yi seto oro aabo lati ri with alaafia joba nibe.

Lori be won ti se ko awon iko amotekun to pos ii lo sibe, fomina ni awon osise ajo alaabo naa to to igba ni won ti ko lo sibe lati satileyin fun awon to wa nibe to wa fikun wipe oko merin miran ni won yio fun iko alaabo naa lati fi maa sise.

O tun salaye wipe won ti pase lati bere eto iforukosile fun idanimo lawon agbegbe naa.

Gomina war o awon to di ipo oselu mu lati maa tete pe akiyesi ijoba si awon ohun ti o ba nsele lagbegbe won.

O wa kedun pely awon molebi to ti padanu eni won nitori oro aabo to mehe.

Lara awon to wa nibi ipade naa lati tiadari ile igbimo asofin ipinle Oyo, awon alakoso, alaga, ati awon omo igbimo lajo-lajo, awon omo ile igbimo asofin ati awon to dipo oselu mu ti won wa lati ekun ibarapa.

 Adebisi/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *