Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Ti Di Ẹ̀bi Pípọ̀ Sí Àwọn Tóní Àrùn COVID-19 Ru Kíkùnà Láti Tẹ̀lé Àwọn Ìlànà Ìlera

Kíkùnà àwọn èyàn nílẹ̀ Nàijírìa láti tẹ̀lé àwọn àlàkelẹ̀ òfin tó rọ̀mọ́ dídànà àrùn covid 19 èyí tí ilésẹ́ tón mójútó ìtànkalẹ̀ rẹ̀ làkalẹ̀ ni ó sokùnfà báwọn náà[sen pọ̀si alákoso fọ́rọ̀ ìròyìn àti àsà, Àlhájì Lai Mohammed ló sọ̀rs yí lásìkò tón kópa lórí ètò ilésẹ́ Radio Nigeria àpapọ̀ ilẹ̀ yí lóní tí wọ́n pè ní Politics Nationwide.

Àlhájì Mohammed tọ́kasi pé pẹ̀lú bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èyàn nílẹ̀ yí se ti kùnà láti mú àwọn ìlànà yi lò bóse yẹ, ló léwu lọ́pọ̀ fún ìlera àwọn èyàn àwùjọ.

Ó tẹnumọ pàtàkì òfin èyí tí àrẹ Buhari fọwọ́sí láipẹ yi, Àlhájì Mohammed wá sèkìlọ̀ fáwọn ilésẹ́ ńláńlá àti lájọlájọ láti tẹ̀lé òfin ọ̀hún nítorí pé ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sófin ni osese kí kélé òfin gbe kó sì rí ẹ̀wọ̀n he.

Net/Afọnja   

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *