Ètò ìfórúkọ sílẹ̀ fún nọ́mbà ìdánimọ̀ ilẹ̀ yí NIN tón lọ lọ́wọ́ àti fífi sọwọ́ sí òpó ẹ̀rọ ìbáraẹnìsọ̀rọ̀ ní wọ́n ti fi ọ̀sẹ̀ mẹ́jọ kún báyi, ti gbèdéke rẹ̀ wa di ọjọ́ kẹfà osù kẹrin ọdún tawàyí.

Nínú àtẹ̀jáde èyí tí àjọ tón mójútó gbígba nọ́mbà ìdánimọ̀ NIN, dìjọ fọwọ́sí ni alákoso fétò ìbáraẹnìsọ̀rọ̀ àti kétò ọrọ ajé, ọ̀mọ̀wé Isa Pantami ló sọ̀rs yí di mímọ̀ lásìkò ìpàdé pọ̀ àwọn tarọkàn lórí ètò ìforúkọ sílẹ̀.

Ó sọ pé sísún síwájú yi ni yófun àwọn èyàn nílẹ̀ Nàijírìa àtàwọn tón gbé ilẹ̀ yí lọ́nà tó bá òfin mu, lásìkò sí láti sọ nọ́mba wọn pọ mọ ti ẹ̀rọ ìbáraẹnìsọ̀rọ̀ wọn.

Àtẹ̀jáde náà jẹ́ kódi mímọ̀ pé ó lé ní milliọnu mkrin dín lọ́gọ́ta nọ́mbà ìdánimọ̀ táwọn òpó ìbáraẹnìsọ̀rọ̀ ti gba láti lò.

Net/Afọnja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *