Yoruba

Gomina Akeredolu Ke Gbajare Lori Awon Ton Nwole Silu Lona Aito

Gomina Ipinle Ondo, Oluwarotimi Akeredolu ti ke gbajare lori bi aleekun se n ba iye awon to n wo ipile naa lona aito latawon enu iloro ori-ile.

O soro yi l’asiko to n’gba alejo Igbakeji Oga-Agba, nilese to nrisi iwole-wode awon eeyan nileyi ekun ZONE F, Dora Amahian, lofisi re nilu Akure.

Zone F yii, lo n mojuto ipinle, Oyo, Osun, Ondo and Ekiti.

Gomina Akeredolu woye pe orile ede Nigeria n padanu ohun pipo nitori awon iwaa odaran latowo awon eeyan to yo wo ile yi lona aito.

Gomina Akeredolu enito daba ibasepo kia-kia laarin awon ajo eleto aabo, wa bebe fun atileyin awon araalu lati wojutu is iwaa kooto awon arin-rinajo tiwon fe sora won di omo onile.

Olurunferanmi Odofin/Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *