Yoruba

Aare Buhari F’awon Agunbaniro Tofakoyo Ni Ise

Aare Muhammadu Buhari ti fun awon agubaniro tootoo ogorun kan ati mewa, nise nileese ijoba apapo ati ebun eko ofe lati le keko siwajusi, lati keko gba oye omowe, leyi keyi ile-eko giga ni Nigeria.

Aare buhari, enito  soro yi, nibi eto, ifami eye danilola fawon agunbaniro towaye lori eto ayelujara fodun 2018-2019, to situn kede ebun owo fun awon agunbaniro tele kan.

O wa kesi awon lajo-lajo ijoba tooro kan, lati ridajupe won tete sise lori awon amin eye naa.

Aare wa kesi awon, to gba amin eye, lati maase kara ninu iwa omoluabi to mu gba amin eye naa.

Adenitan/Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *