Yoruba

Ajo NCC Bere Owo Gbigba Lori Tete Tita

Ajo to nrisi ibara enisoro nile yii, NCC, ti gunle eto ideyele owo, awon onileese ero ibanisoro yoo ma san lori lilo ero ibara eni soro lati fi seto iduna dura nile ifowopamo atawon ileese olookoowo min.

Ninu atejade toludari, f;oro tokan araalu lajo ncc, omowe Ikechukwu Ainde fi sita sope, ajo naa ko nu gbawa lowo awon ile-ifowopamo, fun tite awon number kan fise eto iduna-dura.

Ogbeni Adinde wa sodi mimo pe owo tawon ti n se okoowo tete yoo maa san ni million mewa fun iforukosile naira ati million mewa fun atunse iforukosile tawon to nibudo itaayo naa yoo si maa san egberun lona igba naira, fun iforukosile, ati gberun lona igba naira bakan fun atunse iforukosile ibudo won.

Net/Idogbe 

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *