Yoruba

Won Ti Bura Fun Gomina Akeredolu Fun Saa Eto Isejoba Keji

Won ti bura fun Gomina ipinle Ondo, Ogbeni Rotimi Akeredolu gege bi Gomina Ipinle naa fun saa keji.

Gomina Akeredolu tow obo iwe lago mokanla ku ise die owuro oni.

Igbakeji re titun, Lucky Ayedatiwa, naa je bibura fun lati ropo igbakeji re tele too dije taako ninu eto idibo Gomina to koja nipinle naa.

Akoroyin ileese wa to wa nibi eto naa jabo pe liana abo covid-19, je titele san-san.

Odofin/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *