Yoruba

Akosemose Foro Abo Pe Fun Kiko Awon Omo Nile Eko Alakoobere Nipa Eko Liri Ilana Abo.

Akosemose foro abo nile eko giga vasity Ibadan, Ojogbon Oyesoji Aremu sope o se Pataki kawon omo ile-iwe alakobere nii imo kikun nipa eko lori liana abo lati madinku ba ipenija eto abo to nkoju orileede Nigeria.

Ojogbon Aremu so eyi fawon oniroyin nilu Abuja pelu alaye pe, inife eko bee yoo mu won moo awon ohun toye leka eto abo.

Ojogbon Aremu nii, eto abo to mehee lawon ile-iwe, eyi ti orileede Nigeria nkoju bayii, tin se akoba feto eko ko sai wa kesi ijoba apapo ati tipinle lati sagbekale liana ti yoo wa ojutu si iwa ko to yi.

 Banjo/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *