News Yoruba

Atotodabo Lo Ti Seriyo Lawon Ile Epo Yika Ilu Ibadan

Owon gogo epo gbodekan yika ilu Ibadan, tise olu-lu ipinle Oyo, pelu bi opo ile epo ko se ni epo pentirol ta fawon awako.

Akoroyin ileese Radio Nageria to lo to pinpin isele yi ni agbegbe Moniya, Ojoo, Mokola, Iwo Road, Challenge, Apata, to fi mo agbegbe Orita Apeprin jabo pe ile itaja epo perete lo n ta oja, tawon awako si to latodaabo, lai wo iye ti won nta.

Akoroyin wooye pe, opo olugbe lo peju babi pelu oko won tawon miran sig be kegi lowo.

Owongogo epo yi lo tin sakoba fun iye owo oko tawon oloko ero ngba, ti won si ti fi, ida adota ninu ogorun kun owo ti won ngba tele.

Ninu iforowanilenuwo pelu akoroyin ilese Radio Nigeria awako ero meji, fie sun kan pea won to n ta epo ni won bere owo eyin ki won to ta epo pentrol fun won

Insert

Won war o eka to n mojuto oro epo roobi lati fiya to to je ile epo to ba ko lati ta oja ni iye to yen.

Ibrahim/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *