Yoruba

Ipinle Ogun N Bere Atileyin Ajo NBC for idagbasoke Ere Kusu Tongeji Nibiti Epo Roobi wa.

Gomina Ipinle Ogun, Omo Oba Dapo Abiodun n bere fun atileyin ijoba apapo lati se iranwo fun awon olugbe ere kusu Tongeji nibi ti epo roobi wa.

O soro yi nilu Abeokuta, lasiko iside apero olojo mejii eyi ti ileese to mojuto alaa ile nile yi ati lekun gusu iwoorun seto re.

Gomina Abiodun tokasi pe, isejoba oun mo pe oseese ki epo roobi wa ni erekusu naa, idi niyi teto igbayegbadun awon eeyan ibe sese Pataki.

Saaju ni oludari ajo to n mojuto oro alaa, ogbeni Adamu Adaji so pee to apero naa, ni won se agbekale re kawon torokan, to n mojuto alaa ayika ile yi le gbe liana atele kale ti yo yanju awon ipenija to seese to suyo

Adesida/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *