Yoruba

Oluranlowo Pataki Faare P’efun Igbese Lati Wojutu Si Ise Larin Awon Obinrin

Oluranlowo pataki fun aare f’oro idagbasoke saa ta a wayi, Arabinrin Adejoke Oorelope Adefulure ti pe fun ifowosowopo gbogbo awon t’orokan lati wojutu si isee l’aarin awon obinrin.

O so eyi ninu atejade to fi sita lati s’amin ayajo awon obinrin fun todun yi.

Arabinrin Oorelope-Adefulure kegbajare pe, onira fun opo obinrin lati gbo bukata tooye, nitori ipa arun COVID-19.

O tokasi pe, ijoba apapo ti dahun si opo ipenija awon obinrin nipase owo iranwo pataki f’awon obinrin ese-kuku, lawon ipinle merindinlogoji to wa lorileede yi.

Elizabeth Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *