Home Posts tagged Covid-19
Yoruba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn Gùnlé Ìlanilọ́yẹ̀ Lórí Ẹ̀yà Àrùn Covid-19 Min

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti gùnlé ìlanilọ́yẹ̀ lórí àyẹ̀wò láwọn ìjọba ìbílẹ̀ márun tí àrùn covid-19 ti nwopo pẹ̀lú àmọ̀nràn fáwọn olùgbé ibẹ̀ láti ríì dájú wípé wọn tẹ̀lé ìlànà ìlera lọ́nà àti dáàbòbò ara wọn lórí ẹ̀yà TUNTUN ÀRÙN COVID-19 tí a mọ̀ si Delta. Alákoso fọ́rọ̀ ìlera nípinlẹ̀ Ògùn, Dókítà Tomi Coker ló sọ̀rọ̀ […]Read More...
News Yoruba

Ijoba Apapo Sekilo Fawon Omo Orileede Yi Kan, Lati Yago Kuro Nidi Gigunle Irin-Ajo Lo Sawon Orileede Tarun Covid-19 Eleeketa N Ba Finra

Ijoba apapo orileede yi ti sekilo fawon omo orileede yi, lati yago kuro nidi gigunle awon irinajo lo sawon ilu ti ibesile kokoro aarun covid-19 n bafinra fun igba keta, papa  julo ile India nibi to ti gbile jula. Bakanna, lo tun menuba ile South Africa, Turkey ato rileede Braizil ninu oro igbanniyanju lori oro […]Read More...
Load More