Yoruba

Egbe Osise NLC Tipinle Oyo Darapo Mo Eto Ifehonuhan Lori Aba Atunse Towo Osu

Nibamu pelu ase eyi ti, Agbajopo egbe osise nile yi pa, egbe osise leka ipinle Oyo, ti NLC ati TUC ni won gunle ifehonuhan Alafia lo si ile igbimo asofin.

Ifehonuhan ohun lo bere ni ofisi egbe osise to wa ni Agodi, ti won ginle lati tako aba ofin ti gbimo asofin fun bere bun iyasoto lori gbigba owo osu to kerejulo.

Nigba to n ba awon eeyan soro lenu abawole Sekiteriati, Alaga egbe osise, TUC nipinle yi, Ogbeni Akanni Ogunniran so pe agbarijopo egbe osise yo ri daju pe Aba ofin naa ko di mimulo.

Akoroyin ileese Radio Nigeria jabo pe, eto abo lagbegbe Secretariat lo ti munadoko si lati dena titapa sofin.

   kehinde/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *